Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2019

Lyrics

Tani

Written by Sola Allyson

Produced by Olaitan Dada



Tani mo gbekele ti mo fi n s'ayo

Tani mo gbekele ti mo fi n gbe'se mo ngbe

Tani mo gbekele ti mo fi n yan


Repeat


Adlib: Tani tani gan

Mo ń gbese mo ngbe


Igba eru ba mi sibe mo n s'ayo

(Mo ń s'ayo)

Igba eru ba mi sibe mo n gbe'se mo ngbe

(Mo n gbe'se mo ngbe)

Igba eru ba mi sibe mo n yan


Igbagbo ireti l'o mu mi n s'ayo

(Ayo ninu Baba mi)

Igbagbo ireti l'o mu mi n gbe'se mo ngbe

(Mo n tesiwaju oo)

Igbagbo ireti l'o mu mi n yan


Tani mo gbekele ti mo fi n s'ayo

Baba ni mo gbekele ti mo fi n gbe'se mo ngbe

Oun mo gbekele ti mo fi n yan


Igba eru ba mi sibe mo n s'ayo

(Nitori mo j'omo Baba)

Igba eru ba mi sibe mo n gbe'se mo ngbe

(Mo n gbe'se mo n tesiwaju l'ona naa)

Igba eru ba mi sibe mo n yan


Igbagbo ireti l'o mu mi n s'ayo

(Eni gbeke l'Oluwa kò ni j'ogun ofo)

Igbagbo ireti l'o mu mi n gbe'se mo ngbe

(B'ó ti le wu k'o ri mo n gbe'se mo ngbe)

Igbagbo ireti l'o mu mi n yan


Ninu igbekele aanu ti kii sa

Iyen lo mu mi de'bi o wa titilai

Aanu t'o bà t'o si wa ko le gbòn mi re, bi mi o ba ti jòó re o wa titilai


O wa titilai, o wa titilai

Aanu t'o ba t'o si wa ko le yìn mí nù, bi mi o ba ti joo re o wa titilai


Ore ofe ki n ma lo joo re ni mo nwa sii, ileri t'o se t'aa si maa se ko le ju mi le, aanu t'o mu mi de'bi si wa ko le tan lailai, bi mi o ba ti joo re o wa titilai


O wa titilai o

O wa titilai

O wa kò le tan

O wa titilai

Aanu t'o ba t'o si wa ko le gbòn mí re lailailai, bi mi o ba ti joo re o wa titilai


Ìtònà ni mo gba ki n le maa s'ayo

Iranwo ni mo fe lati maa rin'na yi

Imole k'ó maa tan bi mo ti nlo


Ad lib: Ìtònà ni mo gba

Ìtònà ni mo bèbè fun o

Imole a maa tan

Ìtònà lat'oke wa

Ìtònà k'o wà fun mi l'ona mi

Lati maa rinna yi o


Ìtònà lat'oke wa

Igbekele mi wa ninu Baba oju ò le ti mi lailai

Mo n tesiwaju l'ona naa, mo ng'oke si l'ojojumo ni


Imole k'ó maa tan bi mo ti nlo


Iwaju iwaju l'òpa ebiti mi a maa re si o

Imole k'ó maa tan


Imole k'ó maa tan bi mo ti nlo.




--- www.LRCgenerator.com ---

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status