Igbagbo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
Igba miran o ma se mi bi kin pada seyin
Igba miran o ma se mi bi kin jowo re
Igbati ji aiye ban ja bi pada seyin
Igba tokan mi gboruru bi kin jowo re
Sugbon mom o iwo ni eni ti kin koni sile
Beni mom o iwo ni eni to solododo
Sugbon mo gba iwo ni eni ti kin ko ni sile
Beeni mo gba iwo ni eni to solo dodo
Igbagbo mi duro lori ododo re
Iwo lapata aiye raye ibi isa di mi
Bo kan mi po ruru ko le pase re da lailai
Iwo solododo mo si mo o ni alanu
Igbagbo mi rom o iwo agabara mi
Oke ni mo fo kan si ibi ti iranwo gbe wa
Fun mi okun ati oke wa kin ma se pada seyin
Kin ma sise ninu iriri kin ma se jowo re
Tori mom o iwo ni eni ti kin koni sile
Beeni mom o iwo ni eni to solododo
Tori mo gba iwo ni eni to kin koni sile
Beeni mo gba iwo ni eni to solododo
Iriri aiye a ma fe sona eni ti o ni igbagbo
Sibe mi o gbekele ohun ka leyin agbara re
Ogbon ori eyan ole lo jaja eto to ni lailai
Ko da bokan mi se ye meji
Ileri to se o duro abrahamu sarah won rerin lowo
Tori oda bi pe yeye ni
Nibe won de ti to ppo si kun ibkun pipe
Fun mi lokun atoke wa iwo ni alatileyin
Kin ma subu kin lajo yi ja kin jowo re
Tori mom o iwo ni eni ti kin koni sile
Beeni mom o iwo ni eni to solododo
Tori mo gba iwo ni eni ti kin koni sile
Beeni mo gba eni ti kin solododo
Mo mo daju eni ti kin koni sile beeni mo gba iwo ni
Eni to solo dodo
Tori mo gba iwo ni eni ti kin koni sile
Beeni mo gba eni ti kin solodo