Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2014

Lyrics

Adura mogba fun e ololufe mi

Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi

Oo ni kagbako l'aye oo ni r'ogun akoba


Oo ni s'irin l'aye be oo ni t'oju ile mole

Ainif'okanbale o ni y'odo re lailailailailai

Oo ni m'osi l'aye aye re a ma dara si

Ife eledumare ree e ooo ore mi

O fewa fun re o fewa f'ayo taa ba barawa s'otito

Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s'ise

Iranse alaanu re wa pelu t'emi nwon njo rin po ni

Ibaase 'wo layo pupo latagbala eledumare

Wa inu oluwa aa dun si Ibaase' wo layo pupo

Latagbala eledumare wa o inu oluwa aa dun si wa


Oba ni a lowo a bi'mo

Oba ni a s'owo a j'ere

Oba ni a r'aje jeun

Imole aa ma tan si

Oba ni a lowo a bi'mo

Oba ni a s'owo a j'ere

Oba ni a r'aje jeun

Imole aa ma tan si



Imoran mi ree fun e ooo oloro mi

Imoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gbo

Pe ko maa s'ora se ore mi at'orun s'ora se

Jowo f'arabale ko gb'emi olorun

L'aye ko m'okan at'eti re kuro ninu etan to kun'nu aye

Gbogbo ohun to ma n dan ko ni wura

Joo ma fi ididi w'ola ola aa to ni wa

Fitila ona re o ni ku lailai aye re a ma dara si


Owo o ni wan n'ile wa

Owo Olorun nbe lara wa

Owo Oluwa nba wa lo

Imole a ma tan si

Oba ni a lowo a bi'mo

Oba ni a s'owo a j'ere

Oba ni a r'aje jeun

Imole aa ma tan si



Ope ti mo nda l'ojojumo ree ore okan t'eledua fun mi maa gbo

Modupe mo yin'le f'olu to gbe mi pade alaanu

Mosope mi o kuta l'oju oja ife, eleda lo ba mi se

Alabarin t'eledua yan fun o gangan ni moje

Alabase t'olorun fifun mi gangan ni iwo je

Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l'ayo

Ka sa maa sora se ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se


Oba ni a lowo a bi'mo

Oba ni a s'owo a j'ere

Oba ni a r'aje jeun

Imole aa ma tan si

Oba ni a lowo a bi'mo

Oba ni a s'owo a j'ere

Oba ni a r'aje jeun

Imole aa ma tan si



Ife okan mi ree ore okan mi tipetipe maa gbo

Pe ka je imole

Imole wa ko tan f'araye ri

Ka f'ara wa lowo

Ka jo rin f'olu ka nipa rere f'ayo

Eni waye lai mu'fe orun se asan bansa

Aa r'owo lo aa f'ola we

Ka s'ise taa ran wa wa pa bi fun

Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l'ayo ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se


Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status