Ire Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Ire - Bukola Bekes
...
Ire/3* Nile mi ooo
moo rire gba
lowo oluwa...
Ayo mi kun
EBA mi joo
Jesu ti soro mi dayo(2*)
verse1:
Hallelujah idemi ja
hallelujah mo bori Ogun ese
hallelujah moju asegun lo
ororo Ayo on San nilewa.
chorus.......(2*)
verse2
Sugbon kan nbe laye mi
emi ko femo lato niloo
ire lotun ire losi
he kowa mi ri oooo
eledunmare
maje ori wa gbabode.(2*).
chorus.....(2*).
hymn.... mosinmi le jesu ninu Igbi aye
ire ire ire ire
....,..........,,,,,, ire Ayo
ire Ayo kowa sodo mi
nitoripe
iba nuje kosi loro mii
moodupe
call & rsp
Gbani gbani gbani oo(4*)
Gbani (4*).
Gbagba gba ni to asaa ba
Ogbeja keru o bori eni too Nija
olori aye gbogbo...ooo
Call: Nitori pe agan to kepe oluwa
RSP: Ennnnnnnn.....
Oromo gbejo
ennnnnnmm
afoju to kepe oluwa
Nise loo riran
Aro to keep oluwa
kikia kia lodide koun
Obirin Oni sun eje kepe jesu
Isun eje gbe
notori na
kepeleda ree(2*)
akuku she tire
Olorun iyanu 3*
aba o she oooo
Mogbagbo olorun iyanu
aba o see(2*)
Toripe
koma salagbara biire(2*)
olorun iyanu (2*)
Aba o see. (repeat).
Aso one isoro re di petele
Olorun alewi lese
olorun adegboye.
toripe
koma salagbara biire re ..... 2*
olorun iyanu (2*) repeat.
Asoroko bi ogiri oke
Awi mayewun
Asoro ma taste
asoro maybe
oji lasaru oku ojo kerin dide
...........