Ka Bi O Osi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Ka Bi O Osi - TY Bello & Tope Alabi
...
Kabi ooo osi
Kabi ooo osi
Arugbo ojo
Adagba ma tepa
Kabiiooo osi
We woship u
Kabiooosi
We worship u
Kabiyooosi
Arugbo ojo
Adagba ma tepa
Kabiooooosi
Won mu o lo ledi kon fi ewe akoko le o lori nibe
Kosi awon to gbimo po lati sope e je afi joba
Abi awon wo loduro tan ni wan ma je oba ni idile won gan
Awon wo lo fi o je to fi je oba kan da wa lohun
Tani eni isaju to mu o oowa sinu orun
Tani eni to fa o ni tete won nu aye pe ko wa dade aye
Oya keni kan fi baba tabi iya re han wa ooo are
Kabioooosi
Arugbo ojo adagba ma tepa loruko re
Kabiiooo osi
Oloyun ara re
obi ra re
oso ra re loruko
Ipa ti ose bilere
Eni tio se yi pada
Ite re lorun kin si
Onipotaaa o le ro oo loye
Arugbo ojo ni oo
Adagba ma te pa oooo
Eeh
Iwo ni Kabiiooo osi
Riru omi okun poh eje won ni dake toba lo oto
Iyanri ee lo sua to ba kaye tan se won ni pare
Igba toun gbogbo ta ko ba di wiwo pale
Iwo li ooo ku oo
Arugbo ojo
Oni ilu alu latorun ooo
Eehehehhe Kabiiooo osi
Oko da aye eru ba aye
Pe kilo fe wa ninu ohun
Igba toh da aye tan omu ohun Gbogbo saye e ko ma jo oruko won
Otin gbe ni ibi kan kotan ko orun are nla ni oo ose tu
Ailetu wo aida hun ro aida hunso olugogun ni ooo
Arugbo ojo
adagba mate pa ooo
Iwo ni kabooooisi
Omo mo to mo oyun sinu alaboyun to fori feti fenu si
Ofimu ofohun Gbogbo sibe
Ode di igba kan obi
Se bi bo ba e pe ki mimi oma mi tani je be oo
Iwo ni kabiiiosi
Agba ra re po oju ti ara lo
Iwo lo da ara
Okun re po ko dele pin oni imi iye
Iwo lo mi imi iye si
Amo lasan to pada wa deniyan
Ehhheeeh kabiooo osi
Oba ti n pa oba je
Oba to le ro oba loye to le ni ko ma min mo
Oba ta o gbodo bi bo ba sese ise owo e si
Ojo ro oye mu bee lorun ran lasiko re oo
Agba ra re po oo
Kabiooo osi
Mo ni kabiiio osi
Kabiooo osi
Kaaaaa bioooo si
Alagbada ina alawo tele orun
Ehehehe
Kabi ooo siiii