Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

Lyrics

Olorun Dide (Remix) ft. Seyi Harmony - Adegbodu Twins

...

Oluwa, Máse bá wà wí nínú ìbínú rẹ.

Beni ki o má ṣe na wa ni gbígbóná ìbínúje rẹ.

Olúwa gbó ẹ̀bẹ̀ wá, kí ó sì gbó àdúrà wa, Àmín

Olorun Dákun dide, a nílò iranlowo rẹ baba

Ọluwa dakun dìde, a nílò iranlowo rẹ baba

Ìgbà tá ń lọ yí o wù wá mọ

Bojuwole latorun

Asiko tá ń lọ yio wù wá mon

Jare mú ohun gbogbo bo sípò bàbà.

Ìwọ na lawa kè sì, lowolowo iranlowo nígbà ìpọ́njú

E yí tí ó bawawi yí togẹ̀, síju anu wọlé latorun

Dákun rò pé ìṣe owó rẹ lawa je, anu ń ṣògo lórí idajo

Ọdún npari lọ, a ó mari nkan se

Àbí kini kókó 2020 yí gan, olorin ó rode lọ, kò sì event rara

Gbogbo Party online yí ò ká ń kankan

Ilé ìjọsìn gbogbo lòdì títí pá, a faimo kí Sátánì má lọ gba ìjọba.

Dìde ó dìde ó, dìde ó dìde o

Dìde ó, díde ó, dìde ó dìde o

Dìde ó dìde bàbà, tí ó bá jẹ ẹsẹ dari ẹsẹ ji ni

Ọlọrun Dákun dìde, a nílò iranlowo rẹ baba

Olúwa Dákun dìde, a nílò iranlowo rẹ baba

Ìgbà tá nlo yí ọ wù wá mọ, bojuwole latorun

Asiko tá nlo yí ọ wù wá mọ, jàre mú ohun gbogbo bo sipo baba


Ó yes Lord.

Baba jàre da owó ìbínú dúró

Dákun ṣe ni ó feyi fawa leti

Bí kò ba sẹpe ìwọ Ọlọ́run ń gbẹ̀bẹ̀

Iponju àti ìyàn lo má fà fún wa

Ijoba tá ni ó rán wa lowo

Ẹnu tí wọn nikan na làwọn ju o

Igbe bamubamu layo la wọn ke

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status