Iyin Ye O Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
[ti:06 Iyin Ye O]
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
Iyin ye ile re oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
O gba mi lowo iku
Ore mi otito
Ofi keke ogun aye mi jono
Olugbeja mi ni
Kosi eni to le se o afi iwo
Kabiyesi re e
Mo juba mo fori bale f’oba
Iwo ni iye ologo julo
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
Ofo gbogbo ilekun ide abawole si ogo mi
O jo gbogbo jankariwo
Emi odi won teriba
Okuta ti awon omole kan
Won adi Pataki igun aye
Owo anu re tofi gbami oga
Mo se iba fun eleyinju ife o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
Ona mi la mori ofe lati odo aseda o
Owo olonde ge sonu
Oun ija won loun lo
Emi leri emi logo
Aso tele ni mo je o
Majemu olorun nfoun laye mi
Mofi iyin fun aduro tini gba gba
Emi ni eni ti oluwa fe gan
Ti asi da lare o e
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o
Iyin ye o oba to fe mi
Ogo ye o oba to fe mi
Kabiyesi re o e